Tope Alabi – Eru Ogo Re Bami Oluwa
The well-known Nigerian gospel singer, film music composer and actress “Tope Alabi”, comes through with this awesome praise worship song titled “Eru Ogo Re Bami Oluwa”. Stay blessed as you listen and share.
This Might Be For You 🔥
Download Eru Ogo Re Bami Oluwa by Tope Alabi Mp3, Lyrics & Video
Lyrics: Eru Ogo Re Bami Oluwa by Tope Alabi
Eru Ogo re bami
Eru ogo re bami o
Eleni ogo
Onite ogo
Alade ogo
Ololainu ogo
Elewa ogo
Kikidaogo ogo
Eda Orun fogo fun aramanda ogo to yii won ka
Akodaogo ogo
Ogoninu ogo
Asaju ogo
Igbeyin ogo
Eru ogo re bami o
Boti n gbe ninu ogo
O n Sogo Lori ite o
Ogo lo wo laso
Oloju ogo ni
Eda Orun fogo fun aramanda ogo to yii won ka
Baba ologo julo to da ohun gbogbo pelu ogo.
Boti leruniyi to
Ite idajo taanu togo
Ogo otun iseju si iseju
Ewa ti o lakawe
Nigbogbo igba sigba
Ododo logo re
Awon orile -ede gbogbo nsola Lori ogo re
Olorun to ta sanmo pelu ogo
Iwo lasaju ologo to leruniyi iba baba iba
Call: alogoleru
Response: toloke
Call: eleruniyi
Response: tonile
Call: onile ola
Response: alade ogo
Call: ofi kikida ogo
Download “Tope Alabi” Mp3
- Song
- Tope Alabi
- Artist
- Eru Ogo Re Bami Oluwa
- Genre
- Christian & Gospel Songs
- Format
- Mp3
Free download. Every download counts toward the EverGospel Top 50.
About Eru Ogo Re Bami Oluwa

Listen to more songs by Eru Ogo Re Bami Oluwa, with Mp3 downloads, videos and lyrics.
All 24 songs by Eru Ogo Re Bami OluwaQuestions about “Tope Alabi”
Who sang “Tope Alabi”?
“Tope Alabi” is by Eru Ogo Re Bami Oluwa.
When was “Tope Alabi” published on this site?
“Tope Alabi” was published here on August 3, 2026.
Where can I download “Tope Alabi” Mp3?
You can download “Tope Alabi” free on this page using the download button. It is available on Ever Gospel.
Is there a video for “Tope Alabi”?
Yes. You can watch the official video on this page.




