The well-known Nigerian gospel singer, inspirational song writer and actress “Tope Alabi”, brings to us powerful a song with the title “WAR” where she collaborated with “TY Bello“. Her songs has always been a blessing to lives, and here's another power packed tune.
Download WAR by Tope Alabi and TY Bello Mp3, Lyrics & Video
Lyrics: WAR by Tope Alabi & TY Bello
This is what I hear in my spirit
E dide togun togun
E dide tija tija
E dide alagbara
You May Also Like:
Dide Olorun mi
Ko wa se'ranwo fokan mi
Dide togun togun
Olori ogun
Akanda ogun
Asaju ogun
Akehin ogun labo
Dide alagbara
Dide oni'mole
Dide alagbara
Ko wa se'ranwo fokan wa
Awa o mo yin uruko melo la mo tale pe o
Gbogbo araiye iba mo ori ki re won ba ma kpe o ni gbogbo o jo ni Alagbara asaju okun la lo a kehin okun la bo
Gbingbinikin ojijifi aji kpo o jo iku da okpa kun wo kon ye
Ji kan lu kan kpa olowo ori aiye oni korkoro aiye lo wo
Eji pota bi koiyin gi o jo kpo ke bi ko yegere be ni o oke yo sha ibare oke ti o ye
Iwo ni oke nla aaa arogun ma ti di o arabataribiti aribiti rababa alejo ti sho ni le kun ni kese oni le kaya ka jo
Alabe Noah sa si alabe be le asa wa gbanigbani lo jo ogun le ko gbe omo nija asa omo da je ko gbe omo nija asa omo do osho
Korkoro inu aiye korkoro ode aiye ilekun korkoro ati kankun ati wole tinu ile ti ta ode kabiyiesi olodumare pata pata gbogbo oporogodo
O ro godo gan asiri aiye owun orun o ro godo gan asiri angeli asiri agbagba mele logun o ro godo gan asiri isale ile asiri ile pepe asiri inu awon ofurufuru
Kabiyiesi o olo bi owo bi omi o koja owo aso o wo ja te leke lo olori aiye gbogbo olori eda gbogbo olori angeli
Oba eniyan oba eda gbogbo olori awon agbagba mele logun awon orun won kpo lo repete iwo ni kan ni oga gbogbo won emi inu awon woli mimo
Ada tan atobi tan o koja kika te ekoja riri gigun lai lopin ahile tuwo adan ro adan so adan se olu inu awon orun oke nla o kabiyesi oooo a a gbe o ga