Home » Christian & Gospel Songs » Tope Alabi – Nigbati Mo Ro O

Tope Alabi – Nigbati Mo Ro O

by King David
Evergospel T

The well-known Nigerian gospel singer, film music composer and actress “Tope Alabi”, comes through with this awesome praise worship song titled “Nigbati Mo Ro O”. Stay blessed as you listen and share.

Download Nigbati Mo Ro O Mp3 & Lyrics by

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Nigbati Mo Ro O by

Lati inu oyun
Titi di omo owo o

Igba mo wa lomo owo
Awon ota gba wipe iku o pa mi

Mo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye rara
Baba o sho mi, ore re yi o lakawe

Lati irakoro titi di omo irinse o sho mi
Titi mo fi wa di agbalagba o
Igba ti mo ro, Ise Iyanu re laye mi

Mo wa ri pe o oga o pupo
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,

Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,

Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,

Mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,

Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Ogun ti eniyan ja n'agba, o poju Ogun ewe lo

Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko
Idi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi…

Leave a Reply