Home » Christian & Gospel Songs » Tope Alabi – Adake Dajo

Tope Alabi – Adake Dajo

by King David
Adake Dajo

The well-known Nigerian gospel singer, film music composer and actress “Tope Alabi”, comes through with this awesome praise worship song titled “Adake Dajo”. Stay blessed as you listen and share.

Download Adake Dajo by Mp3, Lyrics & Video

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Adake Dajo by

Ohun gbogbo ti a gb'aye se
On lo da ojiji mo wa
Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro
K'a ye s'esin, k'a ye pe e ni esin, k'a lo ja'wo pata
A o le gan Olorun pelu ‘gbagbo oju tori ko ni le gba wa
A n fi ti'pa gboran si ‘lana esin, ofin Olorun wa d'afieyin
Opo dara loju, iwa won o dokan
T'egbin t'idoti ko je k'adura opo onigbagbo o gba
Ojiji t'Eleda da mo wa, o n s'afihan ohun ikoko o
E o ni le gba'bode f'Olorun, onitohun a wule tan ‘ra e pa
Olorun alawopa, dakun ma wo mi pa
Adake dajo
On lo mo wa o, O n wo wa w'okan
Ohun gbogbo ti a gb'aye se
On lo da ojiji mo wa
Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro
Eemo to wo ‘jo Olorun ti wa bureke, gbogbo aye di ‘ranse Olorun
At'eni Baba ran, at'eni ebi le de
Woli osan gangan, iyen lo bi rere
Ori pepe di ‘gbale egungun
At'alafose at'elepe
Ogo ologo de ku t'on mi wo s'agbara
Igbadi m be labe collar opo won
Awon t'ogun nja t'on tori k'ogun o le se t'on wo ‘nu ijo wa
O ma se arakun laso gbagi logun to n kun ogun won
Ab'e o ri ijo, ki Jesu to de ki ni yio da o
Adake dajo

On lo mo wa o, O n wo wa w'okan
Ohun gbogbo ti a gb'aye se
On lo da ojiji mo wa
Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro
E je k'a bi ‘ra wa leere, gbogbo iranse Olorun pata
Kini idahun si ibeere yi o
Oro ijoba orun ti di ‘waasu igbaani lenu wa
Ere wo lonisowo agba n je ninu ise wa
E gbo ere wo, ere wo, lOluwa n je
A fowoleran O ma n wo wa o
Ko ma ka ‘se mi lai lere kankan
Ki loo ro, ki loo so
Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan
Ta o ba pe omo omo o
Ki loo ro, ki loo so
Ki loo ro, ki loo so
Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan
Ta o ba pe omo omo o
Ki loo ro, ki loo so
T'a ba p'oruko ni'joba orun
T'a pe won titi ti o de kan e o
Eni to n toka s'omo apaadi, at'eyin to mo ‘mo ile ologo
T'on ba p'oruko ni'joba orun, t'on o ka mr census e ki loo ro
Ki loo ro, ki loo so
Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan
Ta o ba pe omo omo o
Ki loo ro, ki loo so
Onigbagbo ka ri mi ete eke
Lati inu ijo je ‘ra wa lese dede
Adura at'aawe odi s'enikeji
Ife ikoko lori pepe si pepe
E o ranti O da ogbon o ju ogbon lo
E o ba lako bi ibon lese-o-gbeji
Ki loo ro, ki loo so
Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan
Ta o ba pe omo omo o
Ki loo ro, ki loo so
Ojo nla, Adajo aye fere de
Aiyiwapada idajo a ro
K'onikaluku lo ye ‘ra e wo
Ibi t'o ba ku si, gb'adura k'o tun se
Ko ma ba di ki loo ro
K'enu ma wo ji, ailesoro
Ki loo ro, ki loo so
Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan
Ta o ba pe omo omo o

Ki loo ro, ki loo so
Eh eh eh eh eh eh mo wi t'emi o, ore ma di'ti
Ko ma di'na orun mo ‘ra e, o ti n f'ami han, Jesu o ni pe de
Eru igi to n be loju re, lo gbe kuro, ko ye tenubole soro
Lo ronu ko pa iwa da, ka si toro fun aanu
K'a ju'wo ju'se k'a tuba f'Olorun, k'a le ba joba, k: a le ka wa mo won
Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun
Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa
O n bo laipe, s'asaro aye re
Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun
Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa
O n bo laipe, s'asaro aye re
Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun
Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa
O n bo laipe, s'asaro aye re

Leave a Comment

0:00
0:00