Home » Christian & Gospel Songs » Tope Alabi – Yes And Amen

Tope Alabi – Yes And Amen

by King David
Yes And Amen

The well-known Nigerian gospel singer, film music composer and actress “Tope Alabi”, comes through with this awesome praise worship song titled “Yes And Amen”. Stay blessed as you listen and share.

Download Yes And Amen Mp3 & Lyrics by

DOWNLOAD HERE

Lyrics: Yes And Amen by

Amin Ase ida a lamo o, Eni ti o ni a padanu
Iba o to to olu Imo o, Eni ti o ni o, ko ni nkankan o (Amin aseda)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o, Eni ti o ni o, ko ni nkankan (Ko ni nkankan)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o (Oooooooo)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan (E ko ni nkankan o)

Mo wa ri foba to ni di da aiye eeee, Ibare mare e, oni gbede orun
Iwo to ni gbogbo aiye ni ikawo Bo ti doyi kato
Iba oni mo to ga ju ee, Baba ni baba se (Amin ase ida mo gbe ba fun)

Amin ase ida la mo o (Eni ti o ni o ke)
Eni ti o ni a padanu (Adanu nla lo pa laye, lorun)
Iba o toto olu imo (A ton ton to, mo ri ba, mori ba o)
Eni ti o ni o ko ni nkankan (Ko ni nkankan)
Eni ti o ni o ko ni nkankan o (E ma ni penre labo)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan (Ko ni kini nkan lagbon)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o (O tan fun laiye lorun o)
Eni ti o ni o (Ee) ko ni nkankan

O da okun, O da oosa
Alara to fi omi se osho Iwo to mo ibi eja gba do odo
Majemu to bu ko ja okun Iyanrin te ka aiye
O da okunkun biri mu, Oga imole oo
Oju orun o ni ilekun oo Ogbe bi mejeeji, lai rin irin ajo
O mu eda gba inu eda waiye Ibi emi ngba lo ba, eni kan o mo
Ajulo o eni ti o wa o ko le mo nkankan (Eni ti o wa ke o)

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o (Ko ri nkankan o o)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan (Afoju san ju oni to hun lo mo gba)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan (Ee)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan (Eee)

Majemu alai lepin n lo je, Ijinle alaile tun wo
Irawo nyo lailai lo nka (beni)
Osupa nse atokun to ba dale (beni o)
Ibi gbogbo la n ti mi ri (beni)
O to lo fara da orun saiye (beni o)
O se ojo otun so da eran (beni)
Osuwon bi oye, otun sotutu (beni o)
Eranko Igbo won lo su a (beni)
Eweko, ewebe igi iyen o se sawa ri na

Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o (Eni ti o ri se e, ko ri nkan)
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan (Ko da ko ri ra e pa be ni)
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o (Ooo)
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan [Beat]

Ose mi da bi ohun, opin mi ni ipin Ti ko Jo ti eni keji
Mi o la le hu, emi ni ami aseda latorun
Adagbeyin ni mi o wa fi mi joba Ohun gbogbo ti o ti ko da
Odami ofunmi ni re, Emi ni beeni, ase olodumare ni
Amin lohun, emi lami, Ayanmo ogo, Ogun mi ni
Eda emi lo fi se ranse mi Akori Iran mi, oju ogo re ni
Mo ni imi ye re ninu, Eni o ri mi, ko ri nkankan
Eee Eni ti o ri mi Ko ri nkankan.

Eni ti o ri mi Ko rise olorun wo E (Eni ti o ri mi ke, ko ri nkan)
Eni ti o ri mi Ko ri nkankan o (E o foju)
Eni ti o ri mi, ko rise olorun wo (Ko ri olodumare, oda mi bi ohun ni)
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan, Eni ti o ri mi, ko ri se olorun wo (Ooooooo)
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan o, Eni ti o ri mi, ko ri se olorun wo
Eni ti o ri mi ko ri nkankan

Ami lawa je, si Iwo amin, Beni ire loje ki aiye wa o
Olorun la min, Amin lon famin wa han
Aiye, atorun lamin yen o, Aseda ni amin
Oro re lo je ki a ma wa, Olorun la min

Amin, Amin, Amin, Amin

Leave a Comment

0:00
0:00