Home » Top Christian Songs » Chidinma – Òsùbà

Chidinma – Òsùbà

by King David
Chidinma Osuba 4

Download “Òsùbà” . It is another highly anticipated gospel mp3 and video song from former secular artist turned gospel music artist Chidinma Ekile. This a song of praise worship with her Yoruba ballad titled “Òsùbà” with the stables of EeZee Conceptz Global. Stay blessed as you stream, listen and share.

Download Òsùbà by Mp3, Lyrics & Video.

DOWNLOAD HERE

Click To Download More Of Chidinma Songs Here

Lyrics: Òsùbà by

(Chant) A to gba ra le oooo
Oooo ooooo

Iberu ko di fun mi
Aya o fo mi o
Alade wura, Olorun to ga ju
Olodoodo
Ta lo to o?
Ta lo ju o lo, Oba mi?
Eni to mo wa
Oba to mo wa
To mohun gbogbo

Osuba Olorun Ijaya
Gbanigbani Olorun a n sa ya
Eni to lemi mi, mo de
Osuba Olorun Ijaya

Chorus
Osuba Olorun Ijaya
Gbanigbani Olorun a n sa ya
Eni to lemi mi, mo de

(Chant) Olodumare oo
Oba akoda aye oo
Ogbigba ti n gba alailara
Asoromayeun oo

O gbeni ni ja
Keru o bo ni ja
O pin okun ni ya
O ji oku dide
Iba re maa re sir
Eleburuike ni o
Eni to mo wa
Oba to mo wa
To mo ohun gbogbo

Chorus
Osuba Olorun Ijaya
Gbanigbani Olorun a n sa ya
Eni to lemi mi
Mo de

Chorus
Osuba Olorun Ijaya
Gbanigbani Olorun a n sa ya
Eni to lemi mi
Mo de

(Chant) Onibu ore oo
Jagun jagun ode orun o
Oba ti n be nibi gbogbo
Apejuba
Asajuba
Osuba re re
Osuba re re
Osuba re re oo

Leave a Comment

0:00
0:00